魔镜歌词网
魔镜歌词网 > 欧美歌手 > Samuel Amazing Ayoade > TSV Live > Worship Experience 1

Samuel Amazing Ayoade



歌词
专辑列表

Samuel Amazing Ayoade

Worship Experience 1

(instruments)

Oluwa, Oluwa wa
Oruko Re ti n'iyin
Ni gbogbo aye
Oruko Re ti n'iyin to

*repeat

Esu gb'Oruko Re, o sa w'ogbo
Aje gb'Oruko Re, o sa w'ogbo
Talaba fi o we ninu awon Olorun
Oluwa, Oluwa
Omo to so mi di ominira
Oruko Re ti n'iyi to
Gbogbo aye n wariri won n teriba fun ntori
更多更详尽歌词 在 ※ Mojim.com 魔镜歌词网
Oruko Re ti niyi to

Chorus:
Oluwa... ... ...

Oju t'on so mi ti ko sun lo
Eti t'on gbo mi ti mo ba kepe
Abiyamo to pon mi ti ko sun lo
Oruko Re ti n'iyi to
Gbogbo aye n wariri won n teriba fun ntori
Oruko Re ti n'iyi to

Chorus:
Oluwa... ... ...